1. Tes 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa kò fẹ ki ẹnyin ki o jẹ òpe, ará, niti awọn ti o sùn, pe ki ẹ má binujẹ gẹgẹ bi awọn iyoku ti kò ni ireti.

1. Tes 4

1. Tes 4:4-18