1. Tes 4:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ ẹnyin si nṣe e si gbogbo awọn ará ti o wà ni gbogbo Makedonia: ṣugbọn awa mbẹ̀ nyin, ará, pe ki ẹnyin ki o mã pọ̀ siwaju si i;

1. Tes 4

1. Tes 4:1-14