1. Tes 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o ba le fi ọkàn nyin balẹ li ailabukù ninu ìwa mimọ́ niwaju Ọlọrun ati Baba wa, nigba atiwá Jesu Kristi Oluwa wa pẹlu gbogbo awọn enia mimọ́ rẹ̀.

1. Tes 3

1. Tes 3:11-13