1. Tes 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin si di alafarawe wa, ati ti Oluwa, lẹhin ti ẹnyin ti gbà ọ̀rọ na ninu ipọnju ọ̀pọlọpọ, pẹlu ayọ̀ Ẹmí Mimọ́:

1. Tes 1

1. Tes 1:1-10