1. Sam 8:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani awa o si dabi gbogbo orilẹ-ède; ki ọba wa ki o si ma ṣe idajọ wa, ki o si ma ṣaju wa, ki o si ma ja ogun wa.

1. Sam 8

1. Sam 8:19-22