1. Sam 8:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio mu awọn ẹrúkunrin nyin, ati ẹrubirin nyin, ati awọn aṣàyàn ọdọmọkunrin nyin, ati awọn kẹtẹkẹtẹ nyin, yio si fi nwọn si iṣẹ ara rẹ̀.

1. Sam 8

1. Sam 8:11-22