1. Sam 8:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio mu ninu oko nyin, ati ninu ọgba ajara nyin, ati ninu igi olifi nyin wọnni, ani eyiti o dara julọ ninu wọn, yio si fi fun awọn ẹrú rẹ̀.

1. Sam 8

1. Sam 8:12-21