1. Sam 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si mu okuta kan, o si gbe e kalẹ lagbedemeji Mispe ati Seni, o si pe orukọ rẹ̀ ni Ebeneseri, wipe: Titi de ihin li Oluwa ràn wa lọwọ́.

1. Sam 7

1. Sam 7:9-17