1. Sam 6:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) APOTI Oluwa wà ni ilẹ awọn Filistini li oṣù meje. Awọn Filistini si pe awọn alufa ati awọn alasọtẹlẹ