1. Sam 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe pe, lẹhin igbati nwọn gbe e lọ tan, ọwọ́ Oluwa si wà si ilu na pẹlu iparun nla, o si pọn awọn enia ilu na loju, ati ọmọde ati agbà, nwọn ni iyọdi.

1. Sam 5

1. Sam 5:1-12