1. Sam 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin ara Benjamini kan sa lati ogun wá o si wá si Ṣilo lọjọ kanna, ti on ti aṣọ rẹ̀ fifaya, ati erupẹ lori rẹ̀.

1. Sam 4

1. Sam 4:5-21