1. Sam 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọ̀RỌ Samueli si wá si gbogbo Israeli: Israeli si jade lọ pade awọn Filistini lati jagun, nwọn do si eti Ebeneseri: awọn Filistini si do ni Afeki.

1. Sam 4

1. Sam 4:1-5