1. Sam 31:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si kú, ati awọn ọmọ rẹ̀ mẹta, ati ẹni ti o rù ihamọra rẹ̀, ati gbogbo awọn ọmọkunrin rẹ̀ li ọjọ kanna.

1. Sam 31

1. Sam 31:2-10