1. Sam 30:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi ati awọn enia ti o wà lọdọ rẹ̀ si gbe ohùn wọn soke, nwọn si sọkun titi agbara kò si si fun wọn mọ lati sọkun.

1. Sam 30

1. Sam 30:1-13