1. Sam 30:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wipe, Ẹ má ṣe bẹ̃, enyin ará mi: Oluwa li o fi nkan yi fun wa, on li o si pa wa mọ, on li o si fi ẹgbẹ-ogun ti o dide si wa le wa lọwọ.

1. Sam 30

1. Sam 30:14-26