1. Sam 30:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu u sọkalẹ, si wõ, nwọn si tànka ilẹ, nwọn njẹ, nwọn nmu, nwọn si njo, nitori ikogun pupọ ti nwọn ko lati ilẹ awọn Filistini wá, ati lati ilẹ Juda.

1. Sam 30

1. Sam 30:6-23