1. Sam 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si tun Samueli pè lẹ̃kẹta. O si dide tọ Eli lọ, o si wipe, Emi nĩ; nitori iwọ pè mi. Eli, si mọ̀ pe, Oluwa li o npe ọmọ na.

1. Sam 3

1. Sam 3:2-13