1. Sam 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si rò gbogbo ọ̀rọ na fun u, kò si pa ohun kan mọ fun u. O si wipe, Oluwa ni: jẹ ki o ṣe eyi ti o dara li oju rẹ̀.

1. Sam 3

1. Sam 3:13-21