1. Sam 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina emi ti bura si ile Eli, pe ìwa-buburu ile Eli li a kì yio fi ẹbọ tabi ọrẹ wẹ̀nù lailai.

1. Sam 3

1. Sam 3:9-18