1. Sam 28:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa yio si fi Israeli pẹlu iwọ le awọn Filistini lọwọ: li ọla ni iwọ ati awọn ọmọ rẹ ọkunrin yio pẹlu mi: Oluwa yio si fi ogun Israeli le awọn Filistini lọwọ́.

1. Sam 28

1. Sam 28:14-25