1. Sam 24:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si mu ẹgbẹdogun akọni ọkunrin ti a yàn ninu gbogbo Israeli, o si lọ lati wá Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ lori okuta awọn ewurẹ igbẹ.

1. Sam 24

1. Sam 24:1-7