1. Sam 24:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Oluwa ki o ṣe onidajọ, ki o si dajọ larin emi ati iwọ, ki o si wò ki o gbejà mi, ki o si gbà mi kuro li ọwọ́ rẹ.

1. Sam 24

1. Sam 24:8-22