1. Sam 24:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Oluwa ki o ṣe idajọ larin emi ati iwọ, ati ki Oluwa ki o gbẹsan mi lara rẹ; ṣugbọn ọwọ́ mi ki yio si lara rẹ.

1. Sam 24

1. Sam 24:3-13