1. Sam 23:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si tun bere lọdọ Oluwa. Oluwa si da a lohùn, o si wipe, Dide, ki o sọkalẹ lọ si Keila, nitoripe emi o fi awọn ara Filistia na le ọ lọwọ.

1. Sam 23

1. Sam 23:1-7