1. Sam 23:28-29 Yorùbá Bibeli (YCE)

28. Saulu si pada kuro ni lilepa Dafidi, o si lọ ipade awọn Filistini: nitorina ni nwọn si se npe ibẹ̀ na ni Selahammalekoti. (ni itumọ rẹ̀, okuta ipinyà.)

29. Dafidi ti goke lati ibẹ lọ, o si joko nibi ti o sapamọ si ni Engedi.

1. Sam 23