1. Sam 23:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NWỌN si wi fun Dafidi pe, Sa wõ awọn ara Filistia mba ara Keila jagun, nwọn si jà ilẹ ipakà wọnni li ole.

1. Sam 23

1. Sam 23:1-5