1. Sam 20:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ki iwọ ki o máṣe mu ãnu rẹ kuro ni ile mi lailai: ki isi ṣe igbati Oluwa ke olukuluku ọtá Dafidi kuro lori ilẹ.

1. Sam 20

1. Sam 20:8-18