1. Sam 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o yo fun onjẹ ti fi ara wọn ṣe alagbaṣe: awọn ti ebi npa kò si ṣe alaini: tobẹ̃ ti àgan fi bi meje: ẹniti o bimọ pipọ si di alailagbara.

1. Sam 2

1. Sam 2:1-11