1. Sam 2:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni Ọlọrun kan tọ Eli wá, o si wi fun u pe, Bayi li Oluwa wi, Gbangba ki emi fi ara hàn ile baba rẹ, nigbati nwọn mbẹ ni Egipti ninu ile Farao?

1. Sam 2

1. Sam 2:25-28