1. Sam 2:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si boju wo Hanna, o si loyun, o bi ọmọkunrin mẹta ati ọmọbinrin meji. Samueli ọmọ na si ndagbà niwaju Oluwa.

1. Sam 2

1. Sam 2:12-22