1. Sam 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iṣe awọn alufa pẹlu awọn enia ni, nigbati ẹnikan ba ṣe irubọ, iranṣẹ alufa a de, nigbati ẹran na nho lori iná, ti on ti ọpa-ẹran oniga mẹta li ọwọ́ rẹ̀.

1. Sam 2

1. Sam 2:10-21