1. Sam 19:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SAULU si sọ fun Jonatani ọmọ rẹ̀, ati fun gbogbo awọn iranṣẹ rẹ̀, pe, ki nwọn ki o pa Dafidi.

1. Sam 19

1. Sam 19:1-8