1. Sam 18:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jonatani si bọ aṣọ ileke ti o wà li ara rẹ̀ o si fi i fun Dafidi, ati ihamọra rẹ̀, titi de idà rẹ̀, ọrun rẹ̀, ati amure rẹ̀.

1. Sam 18

1. Sam 18:2-14