1. Sam 18:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o ba Saulu sọ̀rọ tan, ọkàn Jonatani si fà mọ ọkàn Dafidi, Jonatani si fẹ ẹ bi ontikararẹ̀.

1. Sam 18

1. Sam 18:1-10