1. Sam 17:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn Filistini si duro lori oke kan li apa kan, Israeli si duro lori oke kan li apa keji: afonifoji kan sì wa larin wọn.

1. Sam 17

1. Sam 17:1-4