1. Sam 15:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si ko awọn enia na jọ pọ̀ o si ka iye wọn ni Telaimu, nwọn si jẹ ogun ọkẹ awọn ọkunrin ogun ẹlẹsẹ, pẹlu ẹgbarun awọn ọkunrin Juda.

1. Sam 15

1. Sam 15:1-10