1. Sam 15:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli kò si tun pada wá mọ lati wo Saulu titi o fi di ọjọ ikú rẹ̀: ṣugbọn Samueli kãnu fun Saulu: o si dùn Oluwa nitori on fi Saulu jẹ ọba lori Israeli.

1. Sam 15

1. Sam 15:30-35