1. Sam 15:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si wipe, Mu Agagi ọba awọn ara Amaleki na tọ̀ mi wá nihinyi. Agagi si tọ̀ ọ wá ni idaraya. Agagi si wipe, Nitotọ ikoro ikú ti kọja.

1. Sam 15

1. Sam 15:24-35