1. Sam 15:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si wi fun Samueli pe, Emi ti ṣẹ̀: nitoriti emi ti re ofin Oluwa kọja, ati ọ̀rọ rẹ̀: nitori emi bẹ̀ru awọn enia, emi si gbà ohùn wọn gbọ́.

1. Sam 15

1. Sam 15:19-28