1. Sam 15:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn enia na ti mu ninu ikogun, agutan ati malu, pàtaki nkan wọnni ti a ba pa run, lati fi rubọ si Oluwa Ọlọrun rẹ ni Gilgali.

1. Sam 15

1. Sam 15:17-27