1. Sam 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, emi ranti eyi ti Amaleki ti ṣe si Israeli, bi o ti lumọ dè e li ọ̀na, nigbati on goke ti Egipti jade wá.

1. Sam 15

1. Sam 15:1-3