1. Sam 15:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi kãnu gidigidi ti emi fi Saulu jọba: nitoriti o ti yipada lẹhin mi, kò si mu ọ̀rọ mi ṣẹ. O si ba Samueli ninu jẹ gidigidi; on si kepe Oluwa ni gbogbo oru na.

1. Sam 15

1. Sam 15:2-14