1. Sam 14:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahia ọmọ Ahitubu, arakunrin Ikabodu ọmọ Finehasi, ọmọ Eli, alufa Oluwa ni Ṣilo, ti nwọ̀ Efodu. Awọn enia na kò si mọ̀ pe Jonatani ti lọ.

1. Sam 14

1. Sam 14:1-9