1. Sam 14:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin ti nṣọ́na fun Saulu ni Gibea ti Benjamini wò; nwọn si ri ọpọlọpọ awọn enia na tuka, nwọn si npa ara wọn bi nwọn ti nlọ.

1. Sam 14

1. Sam 14:10-20