1. Sam 14:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn mejeji fi ara wọn hàn fun ogun Filistini: awọn Filistini si wipe, Wõ, awọn Heberu ti inu iho wọn jade wá, nibiti nwọn ti fi ara pamọ si.

1. Sam 14

1. Sam 14:8-15