1. Sam 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Omiran ninu awọn Heberu goke odo Jordani si ilẹ Gadi ati Gileadi. Bi o ṣe ti Saulu, on wà ni Gilgali sibẹ, gbogbo enia na si nwariri lẹhin rẹ̀.

1. Sam 13

1. Sam 13:1-12