1. Sam 13:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li emi ṣe wipe, Nisisiyi li awọn Filistini yio sọkalẹ tọ mi wá si Gilgali, bẹ̃li emi ko iti tù Oluwa loju; emi si tì ara mi si i, mo si ru ẹbọ sisun na.

1. Sam 13

1. Sam 13:7-13