1. Sam 12:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si wi fun awọn enia na pe, Ẹ má bẹ̀ru: ẹnyin ti ṣe gbogbo buburu yi: sibẹ ẹ má pada lẹhin Oluwa, ẹ ma fi gbogbo ọkàn nyin sin Oluwa.

1. Sam 12

1. Sam 12:17-25