1. Sam 12:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si kepe Oluwa, Oluwa si ran ãra ati ojò ni ọjọ na: gbogbo enia si bẹru Oluwa pupọ ati Samueli.

1. Sam 12

1. Sam 12:16-23