1. Sam 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

SAMUELI wi fun gbogbo Israeli pe, Kiye si i, emi ti gbọ́ ohùn nyin, ninu gbogbo eyi ti ẹnyin wi fun mi, emi si ti fi ẹnikan jọba lori nyin.

1. Sam 12

1. Sam 12:1-9